Oriki Iseyin is a melodic poetry that serves as a powerful means of self-expression, celebrating the heritage and identity of the Yoruba people. Oriki Iseyin combines rhythmic chants, vivid imagery, and praise to honor individuals, deities, and ancestral lineage. Passed down through generations orally, it serves as a bridge between the past and the present, preserving Yoruba traditions and values.
Oriki Iseyin In Yoruba
Iseyin Oro, Omo Ebedi moko, Ni bi ti ewe nje ariyeke, Ti popo o nje belewo, Ti igi nje oluwanran, Ti agbado ojo nje t’ opabodi.
Ilu ma gba fere, Kii b’ alejo nibi t’ o tiwa, Osalasala ti f’ owo alejo bomi,
Eyin gbo gambari, E gbo sokoto, E gbo ‘Lorin, E gbo Oyo, E gbo ‘Badan, Sugbon e ko gbo, Ohun ti ilu Mokin nwi
Bi e ba se gege ote, K’ amu t’aseyin kuro, B’o ba d’ojo ere, Ke ran ni s’ebedi moko
Eni ba nfe aso ‘tata ti ile Yoruba, eni ki won kori si Iseyin, Nibi tin won ti nhun gida ninu Aso
Edumare jowo bawa da ilu Iseyin si
Amin, Ase